Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 23:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nisinsinyii, ó tó àkókò fún mi láti kú, gbogbo yín ni ẹ sì mọ̀ dájúdájú ninu ọkàn yín pé, ninu gbogbo àwọn ohun rere tí OLUWA Ọlọrun yín ṣèlérí fun yín, kò sí èyí tí kò mú ṣẹ. Gbogbo wọn patapata ni wọ́n ṣẹ, ẹyọ kan kò yẹ̀ ninu wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 23

Wo Joṣua 23:14 ni o tọ