Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 23:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pẹ́ lẹ́yìn tí OLUWA ti fún Israẹli ní ìsinmi, tí kò sí ogun mọ́ láàrin àwọn ati gbogbo àwọn ọ̀tá tí ó yí wọn ká, Joṣua ti di àgbàlagbà ní àkókò yìí, ogbó sì ti dé sí i;

Ka pipe ipin Joṣua 23

Wo Joṣua 23:1 ni o tọ