Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 22:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa ranti lemọ́lemọ́ láti máa pa gbogbo òfin tí Mose iranṣẹ OLUWA fun yín mọ́, pé kí ẹ fẹ́ràn OLUWA Ọlọrun yín, kí ẹ sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀, ẹ máa pa gbogbo òfin rẹ̀ mọ́, ẹ súnmọ́ ọn, kí ẹ sì máa sìn ín tọkàntọkàn.”

Ka pipe ipin Joṣua 22

Wo Joṣua 22:5 ni o tọ