Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 22:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli gbọ́ pé àwọn ẹ̀yà Reubẹni, ẹ̀yà Gadi ati ìdajì ẹ̀yà Manase ti tẹ́ pẹpẹ kan sí ìhà ibi tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ Israẹli, ní agbègbè odò Jọdani, ní àtiwọ ilẹ̀ Kenaani,

Ka pipe ipin Joṣua 22

Wo Joṣua 22:11 ni o tọ