Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 21:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ni wọ́n fún ní ìlú Ṣekemu, tí ó jẹ́ ìlú ààbò fún àwọn tí wọ́n bá ṣèèṣì pa eniyan, ati àwọn pápá ìdaran rẹ̀ tí ó wà ní agbègbè olókè ti Efuraimu. Wọ́n tún fún wọn ní àwọn ìlú wọnyi, pẹlu àwọn pápá ìdaran tí ó wà ní àyíká wọn: Geseri,

Ka pipe ipin Joṣua 21

Wo Joṣua 21:21 ni o tọ