Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 20:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹni tí ń gbẹ̀san ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ bá ń lé e bọ̀, wọn kò ní fi lé e lọ́wọ́, nítorí pé ó ṣèèṣì pa aládùúgbò rẹ̀ ni, kò sì ní ìkùnsínú sí i tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 20

Wo Joṣua 20:5 ni o tọ