Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kúrò níbẹ̀, wọ́n sá lọ sí orí òkè, wọ́n sì farapamọ́ fún ọjọ́ mẹta, títí tí àwọn tí wọn ń lépa wọn fi pada; nítorí pé wọ́n ti wá wọn káàkiri títí ní gbogbo ojú ọ̀nà, wọn kò sì rí wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 2

Wo Joṣua 2:22 ni o tọ