Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin náà bá dá a lóhùn pé, “Kí OLUWA gba ẹ̀mí wa bí a bá pa yín. Bí o kò bá ṣá ti sọ ohun tí a wá ṣe níhìn-ín fún ẹnikẹ́ni, a óo ṣe ọ́ dáradára, a óo sì jẹ́ olóòótọ́ sí ọ nígbà tí OLUWA bá fi ilẹ̀ náà lé wa lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Joṣua 2

Wo Joṣua 2:14 ni o tọ