Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ fi OLUWA búra fún mi nisinsinyii pé, bí mo ti ṣe yín lóore yìí, bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yin náà yóo ṣe ilé baba mi lóore, kí ẹ sì fún mi ní àmì tí ó dájú.

Ka pipe ipin Joṣua 2

Wo Joṣua 2:12 ni o tọ