Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 19:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ilẹ̀ ẹ̀yà Dani bọ́ mọ́ wọn lọ́wọ́, wọ́n bá lọ gbógun ti ìlú Leṣemu, wọ́n ṣẹgun wọn, wọ́n pa wọ́n, wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn. Wọ́n yí orúkọ Leṣemu pada sí Dani, tíí ṣe orúkọ baba ńlá wọn, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:47 ni o tọ