Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 19:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ààlà náà yípo lọ sí Rama; ó dé ìlú olódi ti Tire, lẹ́yìn náà, ó yípo lọ sí Hosa, ó sì pin sí etíkun. Ninu ilẹ̀ wọn ni Mahalabu, Akisibu;

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:29 ni o tọ