Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 19:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ààlà rẹ̀ wá yípo lọ sí apá ìlà oòrùn, títí dé Beti Dagoni, títí dé Sebuluni ati àfonífojì Ifitaeli ní apá àríwá Betemeki ati Neieli. Lẹ́yìn náà ó tún lọ ní apá ìhà àríwá náà títí dé Kabulu,

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:27 ni o tọ