Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 19:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ kẹta tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Sebuluni. Agbègbè tí ó jẹ́ ìpín tiwọn lọ títí dé Saridi.

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:10 ni o tọ