Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin náà bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò wọn, Joṣua sì kìlọ̀ fún wọn, pé, “Ẹ rin ilẹ̀ náà jákèjádò, kí ẹ sì kọ àpèjúwe rẹ̀ sílẹ̀ wá fún mi. N óo sì ba yín ṣẹ́ gègé níhìn-ín níwájú OLUWA ní Ṣilo.” Àwọn ọkunrin náà bá lọ,

Ka pipe ipin Joṣua 18

Wo Joṣua 18:8 ni o tọ