Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà meje ni wọn yóo pín ilẹ̀ náà sí, àwọn ẹ̀yà Juda kò ní kúrò ní àyè tiwọn ní apá ìhà gúsù, bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn ẹ̀yà Josẹfu tí wọ́n wà ní agbègbè tiwọn ní apá ìhà àríwá.

Ka pipe ipin Joṣua 18

Wo Joṣua 18:5 ni o tọ