Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 18:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá bá wọn ṣẹ́ gègé ní Ṣilo, níwájú OLUWA, bẹ́ẹ̀ ni Joṣua ṣe pín ilẹ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli. Ó fún ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan ní ìpín tirẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 18

Wo Joṣua 18:10 ni o tọ