Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 17:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá dá àwọn ọmọ Josẹfu: ẹ̀yà Efuraimu ati ti Manase lóhùn, ó ní, “Ẹ pọ̀ nítòótọ́, ẹ sì ní agbára, ilẹ̀ kan ṣoṣo kọ́ ni yóo kàn yín,

Ka pipe ipin Joṣua 17

Wo Joṣua 17:17 ni o tọ