Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 17:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹ̀yà Josẹfu lọ bá Joṣua, wọ́n wí fún un pé, “Kí ló dé tí o fi fún wa ní ẹyọ ilẹ̀ kan ṣoṣo gẹ́gẹ́ bí ìpín tiwa, nígbà tí ó jẹ́ pé àwọn eniyan wa pọ̀ gan-an, nítorí pé OLUWA ti bukun wa?”

Ka pipe ipin Joṣua 17

Wo Joṣua 17:14 ni o tọ