Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 15:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó lọ láti àfonífojì Akori títí dé Debiri, ó wá yípo lọ sí apá ìhà àríwá, lọ sí Giligali, tí ó dojú kọ gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Adumimu, tí ó wà ní apá gúsù àfonífojì náà. Lẹ́yìn náà, ó lọ sí ibi odò Enṣemeṣi, ó sì pin sí Enrogeli.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:7 ni o tọ