Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

láti apá etí òkun tí ó kọjú sí ìhà gúsù lọ títí dé àtigun òkè Akirabimu. Ó lọ títí dé Sini, ó tún lọ sí apá gúsù Kadeṣi Banea. Ó kọjá lọ lẹ́bàá Hesironi títí dé Adari, kí ó tó wá yípo lọ sí ìhà Kaka.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:3 ni o tọ