Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 15:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kalebu ṣe ìlérí pé, ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣẹgun Kiriati Seferi tí ó sì gba ìlú náà ni òun yóo fún ní Akisa ọmọ òun, láti fi ṣe aya.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:16 ni o tọ