Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àpèjúwe ìpín tí ó kan ẹ̀yà Juda lára ilẹ̀ tí àwọn ọmọ Israẹli gbà, tí a pín fún wọn gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn nìyí:Ilẹ̀ náà lọ títí dé apá ìhà gúsù, ní ààlà ilẹ̀ Edomu, títí dé aṣálẹ̀ Sini.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:1 ni o tọ