Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ fún Joṣua pé, “Má ṣe bẹ̀rù wọn, nítorí pé ní ìwòyí ọ̀la, òkú wọn ni n óo fi lé Israẹli lọ́wọ́. Dídá ni kí ẹ dá àwọn ẹṣin wọn lẹ́sẹ̀, kí ẹ sì sun gbogbo kẹ̀kẹ́ ogun wọn.”

Ka pipe ipin Joṣua 11

Wo Joṣua 11:6 ni o tọ