Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 11:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Joṣua ṣe gba gbogbo ilẹ̀ náà, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti sọ fún Mose, ó sì pín in fún àwọn ọmọ Israẹli; ní ẹlẹ́yà-mẹ̀yà.Lẹ́yìn náà, wọ́n sinmi ogun jíjà.

Ka pipe ipin Joṣua 11

Wo Joṣua 11:23 ni o tọ