Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, OLUWA fúnra rẹ̀ ni ó mú kí ọkàn wọn le, kí wọ́n sì gbógun ti Israẹli, kí àwọn ọmọ Israẹli lè pa wọ́n run, kí wọ́n má baà ṣàánú wọn, ṣugbọn kí wọ́n pa wọ́n run gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Ka pipe ipin Joṣua 11

Wo Joṣua 11:20 ni o tọ