Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 11:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá yipada, ó gba ìlú Hasori, ó sì fi idà pa ọba wọn, nítorí pé Hasori ni olú-ìlú ìjọba ilẹ̀ náà tẹ́lẹ̀ rí.

Ka pipe ipin Joṣua 11

Wo Joṣua 11:10 ni o tọ