Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 10:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá sọ fún wọn pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì ṣe jẹ́ kí àyà yín já. Ẹ múra, kí ẹ sì ṣe ọkàn gírí, nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni OLUWA yóo ṣe sí gbogbo àwọn ọ̀tá yín, tí ẹ̀ ń bá jà.”

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:25 ni o tọ