Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 10:10 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA mú kí ìpayà bá àwọn ará Amori, nígbà tí wọ́n rí àwọn ọmọ Israẹli, àwọn ọmọ Israẹli bá bẹ̀rẹ̀ sí pa wọ́n ní ìpakúpa ní Gibeoni. Wọ́n lé wọn gba ibi gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Beti Horoni, wọ́n sì pa wọ́n títí dé Aseka ati Makeda.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:10 ni o tọ