Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Adonisedeki, ọba Jerusalẹmu, gbọ́ bí Joṣua ṣe gba ìlú Ai, ati pé ó pa ìlú Ai ati ọba rẹ̀ run, bí ó ti ṣe sí ìlú Jẹriko ati ọba rẹ̀; ati pé àwọn ará Gibeoni ti bá àwọn ọmọ Israẹli dá majẹmu alaafia, wọ́n sì ń gbé ààrin wọn,

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:1 ni o tọ