Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ranti pé mo ti pàṣẹ fún ọ pé kí o múra, kí o sì ṣe ọkàn gírí. Má bẹ̀rù, má sì jẹ́ kí ìrẹ̀wẹ̀sì bá ọkàn rẹ, nítorí pé èmi, OLUWA Ọlọrun rẹ wà pẹlu rẹ níbikíbi tí o bá ń lọ.”

Ka pipe ipin Joṣua 1

Wo Joṣua 1:9 ni o tọ