Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ṣá ti múra, kí o ṣe ọkàn gírí, kí o sì rí i dájú pé o pa gbogbo òfin tí Mose, iranṣẹ mi, fún ọ mọ́. Má ṣe yẹsẹ̀ kúrò ninu rẹ̀ sí ọ̀tún, tabi sí òsì, kí gbogbo ohun tí o bá dáwọ́ lé níbikíbi tí o bá lọ lè máa yọrí sí rere.

Ka pipe ipin Joṣua 1

Wo Joṣua 1:7 ni o tọ