Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní sí ẹni tí yóo lè borí rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ. Bí mo ti wà pẹlu Mose ni n óo wà pẹlu rẹ. N kò ní já ọ kulẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni n kò ní kọ̀ ọ́ sílẹ̀ lae.

Ka pipe ipin Joṣua 1

Wo Joṣua 1:5 ni o tọ