Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni tí ó bá tàpá sí àṣẹ rẹ, tí ó sì kọ̀ láti ṣe ohunkohun tí o bá sọ fún un, pípa ni a óo pa á. Ìwọ ṣá ti múra, kí o sì ṣe ọkàn gírí.”

Ka pipe ipin Joṣua 1

Wo Joṣua 1:18 ni o tọ