Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ lọ káàkiri ibùdó, kí ẹ sì pàṣẹ fún àwọn eniyan náà, pé kí wọn máa pèsè oúnjẹ sílẹ̀, nítorí pé láàrin ọjọ́ mẹta wọn óo la odò Jọdani kọjá láti lọ gba ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun wọn fún wọn.”

Ka pipe ipin Joṣua 1

Wo Joṣua 1:11 ni o tọ