Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jona 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí oòrùn yọ, Ọlọrun mú kí afẹ́fẹ́ ìhà ìlà oòrùn fẹ́, oòrùn sì pa Jona tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi fẹ́rẹ̀ dákú. Ó sọ fún Ọlọrun pé kí ó gba ẹ̀mí òun. Ó ní, “Ó sàn kí n kú ju pé kí n wà láàyè lọ.”

Ka pipe ipin Jona 4

Wo Jona 4:8 ni o tọ