Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jona 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá rán ìtàkùn kan, ó fà á bo ibẹ̀, o sì ṣíji bo orí ibi tí Jona wà kí ó lè fún un ní ìtura ninu ìnira rẹ̀. Inú Jona dùn gidigidi nítorí ìtàkùn yìí.

Ka pipe ipin Jona 4

Wo Jona 4:6 ni o tọ