Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jona 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá ní kí wọn kéde fún àwọn ará Ninefe, pé, “Ọba ati àwọn ìjòyè rẹ̀ pàṣẹ pé, eniyan tabi ẹranko, tabi ẹran ọ̀sìn kankan kò gbọdọ̀ fi ẹnu kan ohunkohun. Wọn kò gbọdọ̀ jẹ, wọn kò sì gbọdọ̀ mu.

Ka pipe ipin Jona 3

Wo Jona 3:7 ni o tọ