Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jona 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bi í pé, “Sọ fún wa, nítorí ta ni nǹkan burúkú yìí fi dé bá wa? Kí ni iṣẹ́ rẹ? Níbo ni o ti wá? Níbo ni orílẹ̀-èdè rẹ? Inú ẹ̀yà wo ni o sì ti wá?”

Ka pipe ipin Jona 1

Wo Jona 1:8 ni o tọ