Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jona 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá gbadura sí OLUWA, wọ́n ní, “A bẹ̀ ọ́, OLUWA, má jẹ́ kí á ṣègbé nítorí ti ọkunrin yìí, má sì ka ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ yìí sí wa lọ́rùn; nítorí bí o ti fẹ́ ni ò ń ṣe.”

Ka pipe ipin Jona 1

Wo Jona 1:14 ni o tọ