Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jona 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù ba àwọn tí wọn ń tu ọkọ̀ náà gidigidi, wọ́n sọ fún un pé, “Kí ni o dánwò yìí?” Nítorí wọ́n mọ̀ pé Jona ń sá kúrò níwájú OLUWA ni, gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ fún wọn.

Ka pipe ipin Jona 1

Wo Jona 1:10 ni o tọ