Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joẹli 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ti ṣẹ́ gègé lórí àwọn eniyan mi,wọ́n ti ta àwọn ọmọkunrin wọn,wọ́n fi owó wọn san owó aṣẹ́wó,wọ́n sì ta àwọn ọmọbinrin wọn,wọ́n fi owó wọn ra ọtí waini.

Ka pipe ipin Joẹli 3

Wo Joẹli 3:3 ni o tọ