Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joẹli 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA kígbe láti Sioni,ó sọ̀rọ̀ láti Jerusalẹmu;ọ̀run ati ayé mì tìtì,ṣugbọn OLUWA ni ààbò fún àwọn eniyan rẹ̀,òun ni ibi ààbò fún Israẹli.

Ka pipe ipin Joẹli 3

Wo Joẹli 3:16 ni o tọ