Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joẹli 2:28 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lẹ́yìn náà, nígbà tí ó bá yá,n óo tú ẹ̀mí mi jáde sára gbogbo eniyan,àwọn ọmọkunrin ati àwọn ọmọbinrinyín yóo máa sọ àsọtẹ́lẹ̀,àwọn àgbààgbà yín yóo máa lá àlá,àwọn ọdọmọkunrin yín yóo sì máa ríran.

Ka pipe ipin Joẹli 2

Wo Joẹli 2:28 ni o tọ