Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joẹli 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Orílẹ̀-èdè kan ti dojú kọ ilẹ̀ mi,wọ́n lágbára, wọ́n pọ̀, wọn kò sì lóǹkà;eyín wọn dàbí ti kinniun.Ọ̀gàn wọn sì dàbí ti abo kinniun.

Ka pipe ipin Joẹli 1

Wo Joẹli 1:6 ni o tọ