Àwọn ẹranko ìgbẹ́ pàápàá ń kígbe sí ọ, Ọlọrun,nítorí gbogbo àwọn odò ti gbẹ tán,àwọn pápá oko sì ti jóná.