Àwọn ẹran ọ̀sìn ń kérora,àwọn agbo mààlúù dààmú,nítorí pé kò sí pápá oko fún wọn;àwọn agbo aguntan pàápàá dààmú.