Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joẹli 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wọ aṣọ ọ̀fọ̀, kí ẹ sì sọkún, ẹ̀yin alufaa,ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn,ẹ̀yin tí ẹ̀ ǹ ṣiṣẹ́ ní ibi pẹpẹ ìrúbọ.Ẹ̀yin òjíṣẹ́ Ọlọrun mi, ẹ wọlé,kí ẹ sì fi aṣọ ọ̀fọ̀ bora sùn,nítorí a ti dáwọ́ ẹbọ ohun jíjẹ ati ẹbọ ohun mímu dúró ní ilé Ọlọrun yín.

Ka pipe ipin Joẹli 1

Wo Joẹli 1:13 ni o tọ