Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 6:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Jobu bá dáhùn pé,

2. “Bí ó bá ṣeéṣe láti wọn ìbànújẹ́ mi,tí a bá sì le gbé ìdààmú mi lé orí ìwọ̀n,

3. ìbá wúwo ju yanrìn etí òkun lọ.Ìdí nìyí tí mo fi ń fi ìtara sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Jobu 6