Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 41:1-6 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Ṣé o lè fi ìwọ̀ fa Lefiatani jáde,tabi kí o fi okùn di ahọ́n rẹ̀?

2. Ṣé o lè fi okùn sí imú rẹ̀,tabi kí o fi ìwọ̀ kọ́ ọ ní àgbọ̀n?

3. Ṣé yóo bẹ̀ ọ́,tabi kí ó fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ bá ọ sọ̀rọ̀?

4. Ṣé yóo bá ọ dá majẹmu,pé kí o fi òun ṣe iranṣẹ títí lae?

5. Ṣé o lè máa fi ṣeré bí ọmọ ẹyẹ,tabi kí o dè é lókùn fún àwọn iranṣẹbinrin rẹ?

6. Ṣé àwọn oníṣòwò lè yọwó rẹ̀?Àbí wọ́n lè pín Lefiatani láàrin ara wọn?

Ka pipe ipin Jobu 41