Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 41:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Ṣé o lè fi ìwọ̀ fa Lefiatani jáde,tabi kí o fi okùn di ahọ́n rẹ̀?

2. Ṣé o lè fi okùn sí imú rẹ̀,tabi kí o fi ìwọ̀ kọ́ ọ ní àgbọ̀n?

Ka pipe ipin Jobu 41